ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 August ojú ìwé 5
  • August 15 Sí 21

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • August 15 Sí 21
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 August ojú ìwé 5

August 15 Sí 21

SÁÀMÙ 102-105

  • Orin 80 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jèhófà Máa Ń Rántí Pé Ekuru Ni Wá”: (10 min.)

    • Sm 103:​8-12​—Jèhófà máa ń ṣàánú wa tá a bá ronú pìwà dà, ó sì máa ń dárí jì wá (w13 6/⁠15 ojú ìwé 20 ìpínrọ̀ 14; w12 7/⁠15 ojú ìwé 16 ìpínrọ̀ 17)

    • Sm 103:​13, 14​—Jèhófà mọ ibi tí agbára wa mọ (w15 4/⁠15 ojú ìwé 26 ìpínrọ̀ 8; w13 6/⁠15 ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 16)

    • Sm 103:​19, 22​—Tá a bá mọyì àánú àti inú rere onífẹ̀ẹ́ Jèhófà, a ó máa ti ipò ọba aláṣẹ rẹ̀ lẹ́yìn (w10 11/⁠15 ojú ìwé 25 ìpínrọ̀ 5; w07 12/⁠1 ojú ìwé 21 ìpínrọ̀ 1)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Sm 102:​12, 27​—Nígbà tí ìbànújẹ́ bá dorí wa kodò, báwo ni àjọṣe tá a ní pẹ̀lú Jèhófà ṣe lè ràn wá lọ́wọ́? (w14 3/⁠15 ojú ìwé 16 ìpínrọ̀ 19 sí 21)

    • Sm 103:13​—Kí nìdí tó fi jẹ́ pé kì í ṣe gbogbo àdúrà wa ni Jèhófà máa ń dáhùn lójú ẹsẹ̀? (w15 4/⁠15 ojú ìwé 25 ìpínrọ̀ 7)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 105:​24-45

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) g16.4 ojú ìwé 10 àti 11​—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá pa dà wá.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) g16.4 ojú ìwé 10 àti 11​—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 164 sí 166 ìpínrọ̀ 3 àti 4​—Ran akẹ́kọ̀ọ́ náà lọ́wọ́ kó lè rí bó ṣe lè fi ohun tó kọ́ sílò.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 91

  • Má Ṣe Gbàgbé Gbogbo Ohun Tí Jèhófà Ti Ṣe fún Ọ (Sm 103:​1-5): (15 min.) Ìjíròrò. Kọ́kọ́ fi fídíò tó wà lórí ìkànnì jw.org/⁠yo han àwọn ará. Àkọlé fídíò náà ni Ọ̀rọ̀ Ara Mi Sú Mi. (Wo abẹ́ NÍPA WA > OHUN TÁ À Ń ṢE.) Lẹ́yìn náà ẹ jíròrò àwọn ìbéèrè yìí: Kí nìdí tó fi yẹ ká máa yin Jèhófà? Nítorí inú rere Jèhófà, àwọn ìbùkún ọjọ́ iwájú wo là ń retí?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 22 ìpínrọ̀ 1 sí 13

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 131 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́