ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 October ojú ìwé 2
  • “Fi Gbogbo Ọkàn-Àyà Rẹ Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Fi Gbogbo Ọkàn-Àyà Rẹ Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ṣé O Gbà Pé Ohun Tó Tọ́ Ni Jèhófà Máa Ń Ṣe?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2022
  • Lo Ìgbàgbọ́ —Kó O Lè Ṣe Ìpinnu Tó Mọ́gbọ́n Dání!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2017
  • Báwo Lo Ṣe Máa Ń Ṣèpinnu?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2016
  • Bóo Ṣe Lè Ṣe Ìpinnu Tó Mọ́gbọ́n Dání
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2001
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 October ojú ìwé 2

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÒWE 1-6

“Fi Gbogbo Ọkàn-àyà Rẹ Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà”

Ọkùnrin kan láyé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì ń gbàdúrà

Jèhófà ló yẹ ká gbẹ́kẹ̀ lé pátápátá. Ìtúmọ̀ orúkọ rẹ̀ jẹ́ ohun tó fi wá lọ́kàn balẹ̀ pé ó máa mú gbogbo ìlérí rẹ̀ ṣẹ láìkù síbi kan. Àdúrà jẹ́ ọ̀nà kan tá a lè gbà fi hàn pé a gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà. Òwe orí 3 fi wá lọ́kàn balẹ̀ pé Jèhófà máa san wá lẹ́san tá a bá gbẹ́kẹ̀ lé e, ọ̀nà tó sì máa gbà ṣe bẹ́ẹ̀ ni pé ó máa ‘mú àwọn ipa ọ̀nà wa tọ́.’

Ẹni tó bá jẹ́ ọlọ́gbọ́n lójú ara rẹ̀ . . .

3:5-7

  • Ẹni tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà . . .

  • máa ń ṣe ìpinnu láìkọ́kọ́ béèrè pé kí Jèhófà tọ́ òun sọ́nà

• máa ń gbára lé èrò tirẹ̀ tàbí ti ayé

  • máa ń ní àjọṣe tímọ́tímọ́ pẹ̀lú rẹ̀ nípasẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, àṣàrò àti àdúrà

  • máa ń wá ìtọ́sọ́nà Ọlọ́run ní ti pé ó máa ń jẹ́ kí ìlànà Bíbélì tọ́ òun sọ́nà tó bá fẹ́ ṣèpinnu

APÁ WO LÓ ṢÀPÈJÚWE OHUN TÍ MO MÁA Ń GBÉ ÀWỌN ÌPINNU MI KÀ?

ÀKỌ́KỌ́: Mo máa ń yan ohun tí mo rò pé ó mọ́gbọ́n dání jù lọ

ÀKỌ́KỌ́: Mo máa ń bẹ Jèhófà pé kó bù kún ìpinnu tí mo bá ṣáà ti ṣe

ÌKEJÌ: Mo máa ń wá ìtọ́sọ́nà Jèhófà nípasẹ̀ àdúrà àti ìdákẹ́kọ̀ọ́

ÌKEJÌ: Mo máa ń yan ohun tó bá àwọn ìlànà Bíbélì mu

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́