October Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé October 2016 Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò October 3 Sí 9 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÒWE 1-6 “Fi Gbogbo Ọkàn-Àyà Rẹ Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà” October 10 Sí 16 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÒWE 7-11 “Má Ṣe Jẹ́ Kí Ọkàn-Àyà Rẹ Yà Bàrá” October 17 Sí 23 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÒWE 12-16 Ọgbọ́n Dára Ju Wúrà Lọ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Bá A Ṣe Lè Máa Dáhùn Lọ́nà Tó Gbéṣẹ́ October 24 Sí 30 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÒWE 17-21 Máa Wà Ní Àlàáfíà Pẹ̀lú Àwọn Ẹlòmíì October 31 Sí November 6 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÒWE 22-26 “Tọ́ Ọmọdékùnrin Ní Ọ̀nà Tí Yóò Tọ̀” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ṣé O Máa Ń Lo Káàdì Ìkànnì JW.ORG?