ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 October ojú ìwé 7
  • October 31 Sí November 6

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • October 31 Sí November 6
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 October ojú ìwé 7

October 31 Sí November 6

Òwe 22-26

  • Orin 88 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Tọ́ Ọmọdékùnrin Ní Ọ̀nà Tí Yóò Tọ̀”: (10 min.)

    • Owe 22:6; 23:24, 25​—Tó o bá fi ìlànà Ọlọ́run kọ́ àwọn ọmọ rẹ, tí wọ́n bá dàgbà wọ́n á láyọ̀, ìgbésí ayé wọn á nítumọ̀, wọ́n á sì mọ̀wà hù (w08 4/1 ojú ìwé 16; w07 6/1 ojú ìwé 31)

    • Owe 22:15; 23:13, 14​—“Ọ̀pá” túmọ̀ sí onírúurú ìbáwí tí àwọn òbí máa ń fún àwọn ọmọ nínú ìdílé (w97 10/15 ojú ìwé 32; it-2-E ojú ìwé 818 ìpínrọ̀ 4)

    • Owe 23:22​—Àwọn ọmọ tó ti dàgbà máa ń jàǹfààní lára ọgbọ́n táwọn òbí wọn ní (w04 6/15 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 1-3; w00 6/15 ojú ìwé 21 ìpínrọ̀ 13)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Owe 24:16​—Báwo ni òwe yìí ṣe fún wa ní ìṣírí láti máa lo ìfaradà lẹ́nu eré ìje ìyè tí à ń sá? (w13 3/15 ojú ìwé 4 àti 5 ìpínrọ̀ 5 sí 8)

    • Owe 24:27​—Ẹ̀kọ́ wo ni Òwe yìí kọ́ wa? (w09 10/15 ojú ìwé 12 ìpínrọ̀ 1)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Owe 22:​1-21

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo káàdì ìkànnì JW.ORG.​—Ìjẹ́rìí àìjẹ́-bí-àṣà.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo káàdì ìkànnì JW.ORG.​—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá, kó o sì jẹ́ kó wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? láti fi kádìí ọ̀rọ̀ rẹ.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv ojú ìwé 179 sí 181 ìpínrọ̀ 18 àti 19

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 101

  • “Ṣé O Máa Ń Lo Káàdì Ìkànnì JW.ORG?”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tá a lè lò, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì tó wà níbẹ̀. Gba àwọn ará níyanjú pé kí wọ́n máa mú káàdì mélòó kan dání ní gbogbo ìgbà tí wọ́n bá fẹ́ jáde nílé.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 3 ìpínrọ̀ 1 sí 12 àti Apá 1​—Òtítọ́ Nípa Ìjọba Ọlọ́run—Pípèsè Oúnjẹ Nípa Tẹ̀mí

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 146 àti Àdúrà

    Ìránnilétí: Jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ gbọ́ orin tuntun yìí lẹ́ẹ̀kan, lẹ́yìn náà, kí ẹ kọ ọ́.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́