ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 October ojú ìwé 4
  • October 17 Sí 23

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • October 17 Sí 23
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 October ojú ìwé 4

October 17 Sí 23

Òwe 12-16

  • Orin 69 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ọgbọ́n Dára Ju Wúrà Lọ”: (10 min.)

    • Owe 16:16, 17​—Ọlọ́gbọ́n èèyàn máa ń kẹ́kọ̀ọ́ ó sì máa ń fi Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run sílò (w07 7/15 ojú ìwé 8)

    • Owe 16:18, 19​—Ọlọ́gbọ́n èèyàn kì í gbéra ga tàbí jọ ara rẹ̀ lójú (w07 7/15 ojú ìwé 8 àti 9)

    • Owe 16:20-24​—Ọlọ́gbọ́n èèyàn máa ń sọ̀rọ̀ rere tó lè ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ (w07 7/15 ojú ìwé 9 àti 10)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Owe 15:15​—Báwo la ṣe lè túbọ̀ láyọ̀ nígbèésí ayé? (g 01/14 ojú ìwé 16)

    • Owe 16:4​—Ọ̀nà wo ni Jèhófà gbà mú kí àwọn ẹni búburú ṣiṣẹ́ “fún ète rẹ̀”? (w07 5/15 ojú ìwé 18 àti 19)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Owe 15:18–16:6

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jo 11:11-14​—Máa fi òtítọ́ kọ́ni. Pe ẹni náà wá sí ìpàdé òpin ọ̀sẹ̀.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 3:1-6; Ro 5:12​—Máa fi òtítọ́ kọ́ni. Pe ẹni náà wá sí ìpàdé òpin ọ̀sẹ̀.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 191 ìpínrọ̀ 18 àti 19​—Pe akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì náà wá sí ìpàdé.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 117

  • “Bá A Ṣe Lè Máa Dáhùn Lọ́nà Tó Gbéṣẹ́”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Múra Ohun Tó O Máa Sọ ní Ìpàdé Sílẹ̀. Lẹ́yìn náà, pe àwọn ọmọdé mélòó kan wá sórí pèpéle kó o sì bi wọ́n pé: Ọ̀nà mẹ́rin wo lèèyàn lè gbà múra ìdáhùn sílẹ̀? Bí wọn kò bá tiẹ̀ pè wá, kí nìdí tá ò fi gbọ́dọ̀ jẹ́ kí ìyẹn ba ayọ̀ wa jẹ́?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 2 ìpínrọ̀ 23 sí 34

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 102 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́