ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 November ojú ìwé 6
  • November 21 sí 27

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 21 sí 27
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 November ojú ìwé 6

November 21-27

ONÍWÀÁSÙ 7-12

  • Orin 41 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Rántí Ẹlẹ́dàá Rẹ Atóbilọ́lá . . . Ní Àwọn Ọjọ́ Tí O Wà Ní Ọ̀dọ́kùnrin”: (10 min.)

    • Onw 12:1​—Ó yẹ kí àwọn ọ̀dọ́ lo àkókò àti okun wọn lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Ọlọ́run (w14 1/15 ojú ìwé 18 ìpínrọ̀ 3 àti ojú ìwé 22 ìpínrọ̀ 1)

    • Onw 12:2-7​—“Àwọn ọjọ́ oníyọnu àjálù” tó máa ń dé bá àwọn arúgbó kì í dí àwọn ọ̀dọ́ lọ́wọ́ (w08 11/15 ojú ìwé 23 ìpínrọ̀ 2; w06 11/1 ojú ìwé 16 ìpínrọ̀ 10)

    • Onw 12:13, 14​—Sísin Jèhófà nìkan ló lè mú kí ìgbésí ayé rẹ dára (w11 11/1 ojú ìwé 21 ìpínrọ̀ 1 sí 6)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Onw 10:1​—Báwo la ṣe lè yẹra fún “ìwà òmùgọ̀”? (w06 11/1 ojú ìwé 16 ìpínrọ̀ 6)

    • Onw 11:1​—Kí ló túmọ̀ sí láti “fọ́n oúnjẹ rẹ sí ojú omi”? (w06 11/1 ojú ìwé 16 ìpínrọ̀ 8)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Onw 10:12–11:10

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 2Ti 3:​1-5 ​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 44:27–45:2 ​—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 25 àti 26 ìpínrọ̀ 18 sí 20​—Pe akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì náà wá sí ìpàdé.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 95

  • “Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​—Ẹ Má Ṣe Fàkókò Ṣòfò Láti Wọnú ‘Ilẹ̀kùn Ńlá’”: (15 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​—Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Yín, kẹ́ ẹ sì jíròrò àpilẹ̀kọ náà.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 4 ìpínrọ̀ 7 sí 15, àti àpótí náà “Bí Ilé Ìṣọ́ Ṣe Ti Ń Gbé Orúkọ Ọlọ́run Lékè,” àti àpótí náà “Ìdí Pàtàkì Tó Fi Yẹ Ká Máa Wàásù”

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 148 àti Àdúrà

    Ìránnilétí: Jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ gbọ́ orin tuntun yìí lẹ́ẹ̀kan, lẹ́yìn náà, kí ẹ kọ ọ́.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́