February 20-26
Aísáyà 58-62
Orin 142 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Pòkìkí Ọdún Ìtẹ́wọ́gbà Níhà Ọ̀dọ̀ Jèhófà”: (10 min.)
Ais 61:1, 2—Ọlọ́run fòróró yan Jésù “láti pòkìkí ọdún ìtẹ́wọ́gbà níhà ọ̀dọ̀ Jèhófà” (ip-2 322 ¶4)
Ais 61:3, 4—Jèhófà pèsè “igi ńlá òdodo” láti ṣe iṣẹ́ rẹ̀ (ip-2 326-327 ¶13-15)
Ais 61:5, 6—“Àwọn ọmọ ilẹ̀ òkèèrè” ń fọwọ́ sowó pọ̀ pẹ̀lú àwọn “àlùfáà Jèhófà” lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù tó tíì gbòòrò jù lọ nínú ìtàn aráyé (w12 12/15 25 ¶5-6)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Ais 60:17—Kí ni díẹ̀ lára àwọn ọ̀nà tí Jèhófà ti gbà mú ìlérí yìí ṣẹ láwọn ọjọ́ ìkẹyìn? (w15 7/15 9-10 ¶14-17)
Ais 61:8, 9—Kí ni “májẹ̀mú tí ó wà fún àkókò tí ó lọ kánrin,” àwọn wo sì ni “àwọn ọmọ”? (w07 1/15 11 ¶5)
Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?
Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 62:1-12
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.1
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.1
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 16 ¶19—Tó bá ṣeé ṣe, ẹ jẹ́ kí ìyá kan bá ọmọbìnrin rẹ̀ kékeré ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Máa Lo Fídíò Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù: (6 min.) Àsọyé. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run? Gba gbogbo àwọn ará níyànjú láti lo fídíò yìí tí wọ́n bá ń fi ìwé tí à ń lò lóṣù March àti April lọ́ni, nígbà àkọ́kọ́ tàbí nígbà ìpadàbẹ̀wò.
“Máa Fọgbọ́n Lo Àwọn Ìtẹ̀jáde Wa”: (9 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Bí A Ṣe Ń Pín Àwọn Ìwé Tó Ṣàlàyé Bíbélì Lórílẹ̀-Èdè Congo.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 8 ¶14-18, àpótí A Mú Kí Iṣẹ́ Ìtumọ̀ Bíbélì Yára Kánkán” àti “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 114 àti Àdúrà