ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 February ojú ìwé 6
  • Jẹ́ Kí Ìrètí Tó O Ní Máa Fún Ẹ Láyọ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jẹ́ Kí Ìrètí Tó O Ní Máa Fún Ẹ Láyọ̀
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jẹ́ Kí Ìrètí Tó O Ní Dá Ẹ Lójú
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2022
  • Ní Ìrètí Nínú Jèhófà Kó o Sì Jẹ́ Onígboyà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2006
  • Ibo Lo Ti Lè Rí Ìrètí Tòótọ́?
    Jí!—2004
  • Ìrètí Tó O Ní Ò Ní Já Ẹ Kulẹ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 February ojú ìwé 6
Ìdílé kan ń múra bí wọ́n ṣe máa gbọ́rọ̀ kalẹ̀ lóde ẹ̀rí nígbà Ìjọsìn Ìdílé wọn

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Jẹ́ Kí Ìrètí Tó O Ní Máa Fún Ẹ Láyọ̀

Ńṣe ni ìrètí dà bí ìdákọ̀ró. (Heb 6:19) Ó máa ń jẹ́ ká lè dúró gbọin tá a bá dojú kọ ìṣòro tó dà bí ijì lílè, tó fẹ́ mú kí ọkọ ìgbàgbọ́ wa sojú dé. (1Ti 1:18, 19) Lára ohun tó lè dà bí ìjì líle nígbèésí ayé wa ni ìjákulẹ̀, àdánù ohun ìní, àìsàn ọlọ́jọ́ pipẹ́, ikú ẹnì kan tá a nífẹ̀ẹ́ tàbí nǹkan míì tó lè ba ìwà títọ́ wa jẹ́.

Ìgbàgbọ́ àti ìrètí máa ń jẹ́ ká lè máa fọkàn yàwòrán àwọn ìlérí tí Ọlọ́run ṣe fún wa. (2Kọ 4:16-18; Heb 11:13, 26, 27) Torí náà, yálà ọ̀run ni ìrètí wa tàbí orí ilẹ̀ ayé, a gbọ́dọ̀ máa ronú lórí àwọn ìlérí Ọlọ́run tó wà nínú Bíbélì, kí ìrètí wa lè máa lágbára sí i. Tá a bá wá dojú kọ ìṣòro tó ń tánni lókun, àá ṣì máa láyọ̀.​—1Pe 1:6, 7.

WO FÍDÍÒ NÁÀ Ẹ MÁA YỌ̀ NÍNÚ ÌRÈTÍ, KÓ O SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Kí nìdí tí Mósè fi jẹ́ àpẹẹrẹ rere tá a lè tẹ̀ lé?

  • Kí ni ojúṣe olórí ìdílé?

  • Kí làwọn nǹkan tẹ́ ẹ lè jíròrò nígbà Ìjọsìn Ìdílé?

  • Báwo ni ìrètí ṣe lè mú kó o fara da àdánwò láìmikàn?

  • Kí ni ò ń fojú sọ́nà fún?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́