ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 March ojú ìwé 2
  • March 6-12

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 6-12
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 March ojú ìwé 2

March 6-12

JEREMÁYÀ 1-4

  • Orin 23 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Mo Wà Pẹ̀lú Rẹ Láti Dá Ọ Nídè”: (10 min.)

    • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jeremáyà.]

    • Jer 1:6​—Jeremáyà lọ́ tìkọ̀ láti gba iṣẹ́ tuntun tí Ọlọ́run yàn fún un (w11 3/15 29 ¶4)

    • Jer 1:​7-10, 17-19​—Jèhófà ṣèlérí fún Jeremáyà pé òun máa fún un lókun òun sì máa ràn án lọ́wọ́ (w05 12/15 24 ¶18; jr 88 ¶14-15)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Jer 2:​13, 18​—Nǹkan burúkú mejì wo làwọn ọmọ Ísírẹ́lì aláìṣòótó ṣe? (w07 3/15 9 ¶8)

    • Jer 4:10​—Ọ̀nà wo ni Jèhófà gbà “tan” àwọn èèyàn rẹ̀? (w07 3/15 9 ¶4)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 4:​1-10

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò tó dá lórí “Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò.” Jẹ́ kí àwọn ará wo àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 149

  • Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù March.

  • A Máa Bẹ̀rẹ̀ Sí I Pín Ìwé Ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi Ní March 18: (8 min.) Àsọyé tí alábòójútó iṣẹ́ ìsìn máa sọ, látinú Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti oṣù February 2016, ojú ìwé 8. Fún ẹnì kọ̀ọ̀kan tó wà nínú àwùjọ ní ìwé ìkésíni náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. Sọ ètò tí ìjọ ṣe láti kárí ìpínlẹ̀ ìwàásù yín.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 9 ¶10-15, àtẹ “Àwọn Tá À Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ń Pọ̀ Sí I” àti àpótí “Jèhófà Ló Mú Kó Ṣeé Ṣe” àti “Bí “Ẹni Tí Ó Kéré” Ṣe Di “Alágbára Ńlá Orílẹ̀-èdè””

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 74 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́