March Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé March 2017 Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò March 6-12 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 1-4 “Mo Wà Pẹ̀lú Rẹ Láti Dá Ọ Nídè” March 13-19 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 5-7 Wọn Ò Ṣe Ohun Tí Jèhófà Fẹ́ Mọ́ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Bá A Ṣe Lè Lo Ìwé Àwọn Wo Ló Ń ṣe Ìfẹ́ Jèhófà Lóde Òní? March 20-26 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 8-11 Tá A Bá Tẹ̀lé Ìtọ́sọ́nà Jèhófà Nìkan La Máa Ṣàṣeyọrí MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Bá A Ṣe Máa Lo Ìwé Tẹ́tí sí Ọlọ́run March 27–April 2 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 12-16 Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Pa Jèhófà Tì MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ran Ìdílé Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Máa Rántí Jèhófà