ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 March ojú ìwé 4
  • March 20-26

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 20-26
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 March ojú ìwé 4

March 20-26

JEREMÁYÀ 8-11

  • Orin 117 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Tá A Bá Ń Tẹ̀ Lé Ìtọ́sọ́nà Jèhófà Nìkan La Máa Ṣàṣeyọrí”: (10 min.)

    • Jer 10:​2-5, 14, 15​—Àwọn ọlọ́run èké láwọn orílẹ̀-èdè ń jọ́sìn (it-1 555)

    • Jer 10:​6, 7, 10-13​—Jèhófà kò dà bí àwọn òrìṣà àwọn orílẹ̀-èdè, òun nìkan ni Ọlọ́run tòótọ́ (w04 10/1 11 ¶10)

    • Jer 10:​21-23​—Àwọn èèyàn kò lè ṣàṣeyọrí láìsí ìtọ́sọ́nà Jèhófà (w15 9/1 15 ¶1)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Jer 9:24​—Irú ìyangàn àti ìfọ́nnu wo ló dára? (w13 1/15 20 ¶16)

    • Jer 11:10​—Níwọ̀n bí àwọn ọ̀tá ti ṣẹ́gun Samáríà tó jẹ́ olú ìlú ìjọba ẹ̀yà mẹ́wàá ti àríwá lọ́dún 740 ṣáájú Sànmánì Kristẹni, kí nìdí tí Jeremáyà fi fi ìjọba ẹ̀yà mẹ́wàá náà kún àwọn tó kéde ìdájọ́ lé lórí? (w07 3/15 9 ¶2)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 11:​6-16

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwé ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi àti kókó iwájú ìwé ìròyìn wp17.2​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwé ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi àti kókó iwájú ìwé ìròyìn wp17.2​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) (ld 4-5 (Akẹ́kọ̀ọ́ lè yan àwòrán tó fẹ́ kí wọ́n jíròrò.)​—Pe ẹni náà wá sí Ìrántí Ikú Kristi.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 101

  • “Bá A Ṣe Máa Lo Ìwé Tẹ́tí sí Ọlọ́run”: (15 min.) Ẹ kọ́kọ́ jíròrò àpilẹ̀kọ náà fún ìṣẹ́jú márùn-ún. Lẹ́yìn náà, jẹ́ káwọn ará wo fídíò kan tó ṣàfihàn bí ẹnì kan ṣe ń lo ojú ìwé 8 àti 9 nínú ìwé pẹlẹbẹ náà láti darí ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. Akẹ́kọ̀ọ́ ń lo ìwé Tẹ́tí sí Ọlọ́run nígbà tí olùkọ́ ń lo ìwé Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé. Gba àwọn ará níyànjú pé káwọn náà máa fojú bá ìwé Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé tó wà lọ́wọ́ wọn lọ.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.)kr “Apá 3—Àwọn Ìlànà Ìjọba Ọlọ́run—Bá A Ṣe Wá Òdodo Ọlọ́run” àti orí 10 ¶1-7

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 35 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́