ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 8-11
Tá A Bá N Tẹ̀ Lé Ìtọ́sọ́nà Jèhófà Nìkan La Máa Ṣàṣeyọrí
Àwa èèyàn kò lágbára, a ò sì láṣẹ láti darí ara wa
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tú ká, torí pé àwọn aṣáájú wọn kò wádìí ọ̀rọ̀ lọ́dọ̀ Jèhófà
Àwọn tó ń tẹ̀lé ìtọ́sọ́nà Jèhófà ń ní àláàfíà, ayọ̀, wọ́n sì máa ń ṣàṣeyọrí