ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 1-4
“Mo Wà Pẹ̀lú Rẹ Láti Dá Ọ Nídè”
Bíi Ti Orí Ìwé
Ó ṣeé ṣe kí Jeremáyà ti fẹ́rẹ̀ẹ́ pé ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n [25] nígbà tí Jèhófà yàn án láti di wòlíì. Jeremáyà ronú pé òun ò tóótun láti ṣe iṣẹ́ náà, àmọ́ Jèhófà mú un dá a lójú pé òun máa tì í lẹ́yìn.
647
Jeremáyà di wòlíì
607
Jerúsálẹ́mù pa run
580
Ìwé kíkọ parí
Gbogbo déètì jẹ́ ṣáájú Sànmánì Kristẹni