ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 March ojú ìwé 3
  • March 13-19

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 13-19
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 March ojú ìwé 3

March 13-19

JEREMÁYÀ 5-7

  • Orin 66 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Wọn Ò Ṣe Ohun Tí Ọlọ́run Fẹ́ Mọ́”: (10 min.)

    • Jer 6:​13-15​—Jeremáyà tú àṣírí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (w88 4/1 11-12 ¶7-8)

    • Jer 7:​1-7​—Jèhófà gbìyànjú láti mú kí wọ́n ronú pìwà dà (w88 4/1 12 ¶9-10)

    • Jer 7:​8-15​—Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì rò pé Jèhófà kò ní ṣe ohunkóhun (jr 21 ¶12)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Jer 6:16​—Kí ni Jèhófà ń rọ àwọn èèyàn rẹ̀ láti ṣe? (w05 11/1 23 ¶11)

    • Jer 6:​22, 23​—Kí nìdí tá a fi lè sọ pé àwọn èèyàn kan “ń bọ̀ láti ilẹ̀ àríwá”? (w88 4/1 13 ¶15)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 5:26–6:5

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-36​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-36​—Jíròrò “Rò Ó Wò Ná.” Pe ẹni náà wá sí Ìrántí Ikú Kristi.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jl ẹ̀kọ́ 1​—Pe ẹni náà wá sí Ìrántí Ikú Kristi.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 125

  • “Bá A Ṣe Lè Lo Ìwé Àwọn Wo Ló Ń ṣe Ìfẹ́ Jèhófà Lóde Òní?”: (15 min.) Ẹ kọ́kọ́ jíròrò àpilẹ̀kọ náà fún ìṣẹ́jú márùn-ún. Lẹ́yìn náà, jẹ́ káwọn ará wo fídíò kan tó máa jẹ́ ká rí bá a ṣe lè jíròrò ẹ̀kọ́ 8 pẹ̀lú akẹ́kọ̀ọ́, kẹ́ ẹ sì sọ̀rọ̀ lórí rẹ̀. Gba gbogbo àwọn tó ní ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì níyànjú pé kí wọ́n máa lo ìwé yìí lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 9 ¶16-21, àti àpótí “ÌWÉ ÀṢÀRÒ KÚKÚRÚ MÉJÌ YÍ ẸNI MÉJÌ LỌ́KÀN PA DÀ NÍ ÀGBÈGBÈ AMAZON” àti “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?”

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 10 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́