ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 5-7
Wọn Ò Ṣe Ohun Tí Ọlọ́run Fẹ́ Mọ́
Jeremáyà fi ìgboyà tú àṣírí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti ìwà àgàbàgebè wọn
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ka tẹ́ńpìlì sí oògùn ajẹ́bíidán tó máa dáàbò bò wọ́n
Jèhófà jẹ́ kí wọ́n mọ̀ pé àwọn ẹbọ tí wọ́n ń rú kò lè bo ìwà àìtọ́ wọn mọ́lẹ̀
Bi ara rẹ pé: Báwo ló ṣe lè dá mi lójú pé ìjọsìn mi bá ìfẹ́ inú Jèhófà mu àti pé kì í ṣe ìjọsìn ojú lásán?
Jeremáyà dúró lẹ́nu ọ̀nà ilé Jèhófà