May 15-21
Jeremáyà 39-43
Orin 133 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jèhófà Máa San Olúkúlùkù Lẹ́san Níbàámu Pẹ̀lú Iṣẹ́ Rẹ̀”: (10 min.)
Jer 39:4-7—Sedekáyà jìyà nítorí pé ó ṣàìgbọ́ràn sí Jèhófà (it-2 1228 ¶4)
Jer 39:15-18—Jèhófà fi hàn pé òun mọyì bí Ebedi-mélékì ṣe gbẹ́kẹ̀ lé òun (w12 5/1 31 ¶5)
Jer 40:1-6—Jèhófà tọ́jú Jeremáyà ìránṣẹ́ rẹ̀ olóòótọ́ (it-2 482)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Jer 42:1-3; 43:2, 4—Kí la rí kọ́ látinú àṣìṣe Jóhánánì? (w03 5/1 10 ¶10)
Jer 43:6, 7—Báwo ni ìṣẹ̀lẹ̀ tí àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí sọ̀rọ̀ nípa ẹ̀ ṣe ṣe pàtàkì tó? (it-1 463 ¶4)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 40:11–41:3
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 46:10—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni. Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣi 12:7-9, 12—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni. Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 153 ¶19-20—Pe ẹni náà wá sí ìpàdé.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Jèhófà Kì Í Gbàgbé Ìfẹ́ Tá A Fi Hàn” (Sm 71:18): (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, Jèhófà Kì Í Gbàgbé Ìfẹ́ Tá A Fi Hàn.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 12 ¶16-23, àwọn àpótí ““Ó Yà Wá Lẹ́nu Gan-an”” àti “Ìbẹ̀wò Ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀ Tó Sèso Rere”; àpótí àtúnyẹ̀wò “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 123 àti Àdúrà