May Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—ìwé ìpàdé May 2017 Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò May 1-7 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 32-34 Àmì Tó Fi Hàn Pé Jèhófà Máa Mú Ísírẹ́lì Padà Bọ̀ Sípò May 8-14 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 35-38 Ebedi-mélékì Jẹ́ Onígboyà àti Onínúure MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Bá A Ṣe Lè Máa Bójú Tó Àwọn Ibi Ìjọsìn Wa May 15-21 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 39-43 Jèhófà Máa San Olúkúlùkù Lẹ́san Níbàámu Pẹ̀lú Iṣẹ́ Rẹ̀ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jèhófà Kì Í Gbàgbé Ìfẹ́ Tá A Fi Hàn May 22-28 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 44-48 Má Ṣe “Wá Àwọn Ohun Ńláńlá fún Ara Rẹ” May 29-June 4 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 49-50 Jèhófà Ń Bù Kún Àwọn Onírẹ̀lẹ̀ Ó sì Ń Fìyà Jẹ Àwọn Agbéraga