ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 May ojú ìwé 6
  • May 22-28

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • May 22-28
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 May ojú ìwé 6

May 22-28

Jeremáyà 44-48

  • Orin 70 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Má Ṣe ‘Wá Àwọn Ohun Ńláńlá fún Ara Rẹ’”: (10 min.)

    • Jer 45:2, 3​—Èrò òdì tó gba Bárúkù lọ́kàn kó wàhálà bá a (jr 104-105 ¶4-6)

    • Jer 45:4, 5a​—Jèhófà fìfẹ́ tọ́ Bárúkù sọ́nà (jr 103 ¶2)

    • Jer 45:5b​—Ọlọ́run dá ẹ̀mí Bárúkù sí torí pé ó gbájú mọ́ àwọn ohun tó ṣe pàtàkì jù (w16.07 8 ¶6)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Jer 48:13​—Kí nìdí tí ojú á fi ti àwọn ọmọ Móábù nítorí Kémóṣì? (it-1 430)

    • Jer 48:42​—Kí nìdí tí àsọtẹ́lẹ̀ Jèhófà pé ìlú Móábù máa pa run fi mú kí ìgbàgbọ́ wa túbọ̀ lágbára? (it-2 422 ¶2)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 47:1-7

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) hf​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) hf​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 199 ¶9-10​—Ní ṣókí, kọ́ akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì rẹ bó ṣe lè ṣe ìwádìí nípa ìṣòro kan tó ní.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 150

  • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​—Ẹ Má Ṣe Máa Wá Àwọn Ohun Ńláńlá fún Ara Yín: (15 min.) Ìjíròrò. Lẹ́yìn náà, jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé​—Kí Ni Mo Fẹ́ Fi Ayé Mi Ṣe?​—Ìrírí.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr “Apá 4​—Ìjọba Ọlọ́run Jagun Mólú—A Fi Ìdí Ìhìn Rere Múlẹ̀ Lọ́nà Òfin,” orí 13 ¶1-10

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 17 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́