ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 47
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jeremáyà

      • Àsọtẹ́lẹ̀ lórí àwọn Filísínì (1-7)

Jeremáyà 47:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 25:17, 20; Isk 25:15, 16; Emọ 1:6; Sef 2:4; Sek 9:5, 6

Jeremáyà 47:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, Kírétè.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 25:17, 20; Emọ 1:8; Sef 2:5
  • +Isk 26:2; Emọ 1:9, 10
  • +Ais 23:1, 4; Jer 25:17, 22; 27:2, 3; Isk 28:21; Joẹ 3:4
  • +Jẹ 10:13, 14; Di 2:23

Jeremáyà 47:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn ni pé wọ́n á fá irun orí wọn torí pé wọ́n ń ṣọ̀fọ̀ àti pé ìtìjú bá wọn.

  • *

    Tàbí “pẹ̀tẹ́lẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sef 2:4
  • +Di 14:1; Jer 16:6

Jeremáyà 47:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:41

Jeremáyà 47:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 25:16

Àwọn míì

Jer. 47:1Jer 25:17, 20; Isk 25:15, 16; Emọ 1:6; Sef 2:4; Sek 9:5, 6
Jer. 47:4Jer 25:17, 20; Emọ 1:8; Sef 2:5
Jer. 47:4Isk 26:2; Emọ 1:9, 10
Jer. 47:4Ais 23:1, 4; Jer 25:17, 22; 27:2, 3; Isk 28:21; Joẹ 3:4
Jer. 47:4Jẹ 10:13, 14; Di 2:23
Jer. 47:5Sef 2:4
Jer. 47:5Di 14:1; Jer 16:6
Jer. 47:6Di 32:41
Jer. 47:7Isk 25:16
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jeremáyà 47:1-7

Jeremáyà

47 Ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ nìyí fún wòlíì Jeremáyà nípa àwọn Filísínì,+ kí Fáráò tó pa Gásà run. 2 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí:

“Wò ó! Omi ń bọ̀ láti àríwá.

Ó máa di ọ̀gbàrá tó kún àkúnya.

Á sì kún bo ilẹ̀ náà àti gbogbo ohun tó wà lórí rẹ̀,

Pẹ̀lú ìlú náà àti àwọn tó ń gbé inú rẹ̀.

Àwọn ọkùnrin á figbe ta,

Gbogbo ẹni tó ń gbé ilẹ̀ náà á sì pohùn réré ẹkún.

 3 Nígbà tí pátákò àwọn akọ ẹṣin rẹ̀ bá ń kilẹ̀,

Tí kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ ń dún

Tí àgbá kẹ̀kẹ́ rẹ̀ ń rọ́ gìrìgìrì,

Àwọn bàbá kò tiẹ̀ ní bojú wẹ̀yìn wo àwọn ọmọ wọn,

Nítorí ọwọ́ wọn ti rọ,

 4 Nítorí ọjọ́ ń bọ̀ tí gbogbo Filísínì máa pa run;+

Gbogbo olùrànlọ́wọ́ tó ṣẹ́ kù ní Tírè+ àti Sídónì+ la máa gé kúrò.

Nítorí Jèhófà máa pa àwọn Filísínì run,

Àwọn tó ṣẹ́ kù láti erékùṣù Káfítórì.*+

 5 Orí pípá* máa dé bá Gásà.

A ti pa Áṣíkẹ́lónì lẹ́nu mọ́.+

Ìwọ àṣẹ́kù àfonífojì* wọn,

Ìgbà wo lo máa kọ ara rẹ lábẹ dà?+

 6 Áà! Idà Jèhófà!+

Ìgbà wo lo máa tó gbé jẹ́ẹ́?

Pa dà sínú àkọ̀ rẹ.

Sinmi, kí o sì dákẹ́.

 7 Báwo ló ṣe máa gbé jẹ́ẹ́

Nígbà tí Jèhófà ti pàṣẹ fún un?

Ó ti yàn án pé kí ó gbéjà ko

Áṣíkẹ́lónì àti etí òkun.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́