Diutarónómì 32:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Tí mo bá pọ́n idà mi tó ń kọ mànà,Tí mo sì múra ọwọ́ mi sílẹ̀ láti ṣèdájọ́,+Màá san àwọn ọ̀tá+ mi lẹ́san,Màá sì fìyà jẹ àwọn tó kórìíra mi.
41 Tí mo bá pọ́n idà mi tó ń kọ mànà,Tí mo sì múra ọwọ́ mi sílẹ̀ láti ṣèdájọ́,+Màá san àwọn ọ̀tá+ mi lẹ́san,Màá sì fìyà jẹ àwọn tó kórìíra mi.