ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 32-34
Àmì Tó Fi Hàn Pé Jèhófà Máa Mú Ísírẹ́lì Padà Bọ̀ Sípò
Bíi Ti Orí Ìwé
Jeremáyà ṣe àwọn ohun tó yẹ nígbà tó fẹ́ ra pápá.
Jèhófà ṣèlérí fún àwọn tó wà nígbèkùn pé tí wọ́n bá gba ìbáwí, òun máa dárí jì wọ́n, wọ́n á sì pa dà sí Ísírẹ́lì; ìyẹn fi hàn pé ẹni rere ni Jèhófà.