June 12-18
ÌDÁRÒ 1-5
Orin 128 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ẹ̀mí Ìdúródeni Ń Jẹ́ Ká Ní Ìfaradà”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìdárò.]
Ida 3:20, 21, 24—Jeremáyà fi hàn pé òun ní ẹ̀mí ìdúródeni, ó sì gbẹ̀kẹ̀ lé Jèhófà (w12 6/1 14 ¶3-4; w11 9/15 8 ¶8)
Ida 3:26, 27—Tá a bá ń fara da àdánwò ìgbàgbọ́ ní báyìí, èyí á jẹ́ ká lè kojú àwọn ìṣòro tó ṣì ń bọ̀ lọ́jọ́ iwájú (w07 6/1 11 ¶4-5)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Ida 2:17—“Àsọjáde” wo ní pàtàkì ni Jèhófà mú ṣẹ sórí Jerúsálẹ́mù? (w07 6/1 9 ¶4)
Ida 5:7—Ǹjẹ́ Jèhófà máa ń mú káwọn èèyàn jìyà ẹ̀ṣẹ̀ táwọn baba ńlá wọn ṣẹ̀? (w07 6/1 11 ¶1)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ida 2:20–3:12
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.3—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.3—Pe ẹni náà wá sí àwọn ìpàdé wa.
Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w11 9/15 9-10 ¶11-13—Àkòrí: Jèhófà Ni Ìpín Mi.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ: (8 min.) Tàbí kẹ́ ẹ jíròrò “Lẹ́tà Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí” tó wà nínú Ìwé Ọdọọdún. (yb17 2-5)
Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù June 2017.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 13 ¶33-34, àpótí “Àwọn Ẹjọ́ Pàtàkì Tí A Jàre Rẹ̀ Ní Ilé Ẹjọ́ Gíga Tó Mú Ká Lè Túbọ̀ Máa Wàásù Ìjọba Ọlọ́run,” àtúnyẹ̀wò “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 100 àti Àdúrà