June Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, June 2017 Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò June 5-11 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JEREMÁYÀ 51-52 Gbogbo Ọ̀rọ̀ Jèhófà Máa Ń Ṣẹ Láìkù Síbì Kan MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Báwo Ni Ìgbàgbọ́ Rẹ Nínú Àwọn Ìlérí Jèhófà Ṣe Lágbára Tó? June 12-18 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌDÁRÒ 1-5 Ẹ̀mí Ìdúródeni Ń Jẹ́ Ká Ní Ìfaradà June 19-25 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 1-5 Inú Ìsíkíẹ́lì Dùn Láti Kéde Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Ìwàásù Ìhìn Rere Máa Fún Ẹ Láyọ̀ June 26–July 2 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 6-10 Ṣé O Máa Wà Lára Àwọn Tá A Máa Sàmì Sí Láti Là Á Já? MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Tẹ̀ Lé Àwọn Ìlànà Jèhófà Nínú Ìwà àti Ìṣe Rẹ