June 26–July 2
ÌSÍKÍẸ́LÌ 6-10
Orin 141 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ṣé O Máa Wà Lára Àwọn Tá A Máa Sàmì Sí Láti Là Á Já?”: (10 min.)
Isk 9:1, 2—Ìran tí Ìsíkíẹ́lì rí kọ́ wa ní ẹ̀kọ́ pàtàkì (w16.06 16-17)
Isk 9:3, 4—Tó bá di àkókò kan nígbà tí ìpọ́njú ńlá bá ń lọ lọ́wọ́, Jésù máa sàmì sí àwọn tó bá fetí sí ìhìn rere láti là á já
Isk 9:5-7—Jèhófà máa pa àwọn ẹni burúkú run, ṣùgbọ́n ó máa dá àwọn olódodo sí
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Isk 7:19—Báwo ni ẹsẹ yìí ṣe lè mú ká gbáradì fún ohun tó ń bọ̀ wá ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú? (w09 9/15 23 ¶10)
Isk 8:12—Báwo ni ẹsẹ yìí ṣe fi hàn pé àìnígbàgbọ́ lè mú kéèyàn bẹ̀rẹ̀ sí í hùwà tí kò dáa? (w11 4/15 26 ¶14)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 8:1-12
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣi 4:11—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 11:5; 2Kọ 7:1—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 127 ¶4-5—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Máa Tẹ̀ Lé Àwọn Ìlànà Jèhófà Nínú Ìwà àti Ìṣe Rẹ”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Ọkọ Kan, Aya Kan.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 14 ¶8-14, àpótí “‘Ikú Rẹ̀ Gbé Orúkọ Ọlọ́run Gaʼ”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 33 àti Àdúrà