June 19-25
ÌSÍKÍẸ́LÌ 1-5
Orin 75 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Inú Ìsíkíẹ́lì Dùn Láti Kéde Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìsíkíẹ́lì.]
Isk 2:9–3:2—Ìsíkíẹ́lì jẹ àkájọ ìwé “orin arò àti ìkédàárò àti ìpohùnréré ẹkún” (w08 7/15 8 ¶6-7; it-1 1214)
Isk 3:3—Ìsíkíẹ́lì mọyì bí Jèhófà ṣe yan òun láti jẹ́ wòlíì (w07 7/1 12 ¶3)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Isk 1:20, 21, 26-28—Kí ni kẹ̀kẹ́ ẹṣin òkè ọ̀run ṣàpẹẹrẹ? (w07 7/1 11 ¶6)
Isk 4:1-7—Ṣé lóòótọ́ ni Ìsíkíẹ́lì ṣe àṣefihàn bí àwọn ọ̀tá ṣe máa sàga ti Jerúsálẹ́mù? (w07 7/1 12 ¶4)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 1:1-14
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-32—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-32—Jẹ́ kí onílé wo fídíò náà, Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìdílé Rẹ Lè Jẹ́ Aláyọ̀, kó o sì fún un ní ìwé pẹlẹbẹ náà.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 143 ¶20-21—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Ìwàásù Ìhìn Rere Máa Fún Ẹ Láyọ̀”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, Wàá Láyọ̀ Tó O Bá Ń Kẹ́kọ̀ọ́ Tó O sì Ń Ṣàṣàrò.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 14 ¶1-7
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 32 àti Àdúrà