ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 July ojú ìwé 2
  • July 3-9

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • July 3-9
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 July ojú ìwé 2

July 3-9

Ìsíkíẹ́lì 11-14

  • Orin 52 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ṣé O Máa Ń Jẹ́ Kí Jèhófà Tọ́ Ẹ Sọ́nà?”: (10 min.)

    • Isk 11:​17, 18​—Jèhófà ṣèlérí pé òun máa mú ìjọsìn tòótọ́ pa dà bọ̀ sípò (w07 7/1 11 ¶4)

    • Isk 11:19​—Jèhófà lè jẹ́ ká túbọ̀ máa fòye mọ àwọn ohun tó fẹ́ ká ṣe (w16.05 15 ¶9)

    • Isk 11:20​—Jèhófà fẹ́ ká máa fi ohun tí à ń kọ́ sílò

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Isk 12:​26-28​—Kí ni àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí sọ pé àwa ìránṣẹ́ Jèhófà ní láti ṣe? (w07 7/1 13 ¶8)

    • Isk 14:​13, 14​—Kí la rí kọ́ nínú bá a ṣe dárúkọ àwọn tó wà nínú ẹsẹ Bíbélì yìí? (w16.05 26 ¶13; w07 7/1 13 ¶9)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 12:​1-10

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò tó dá lórí “Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò.” Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 154

  • Ohun tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ: (15 min.) Tàbí kẹ́ ẹ jíròrò ohun tẹ́ ẹ kọ́ nínú Ìwé Ọdọọdún. (yb17 41-43)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 14 ¶15-23, àpótí “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?”

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 43 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́