July Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé July 2017 Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò July 3-9 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 11-14 Ṣé O Máa Ń Jẹ́ Kí Jèhófà Tọ́ Ẹ Sọ́nà? July 10-16 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 15-17 Ṣé O Máa Ń Mú Ìlérí Rẹ Ṣẹ? July 17-23 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 18-20 Tí Jèhófà Bá Ti Dárí Ẹ̀ṣẹ̀ Jini, Ṣé Ó Máa Ń Gbàgbé Rẹ̀? MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ṣé O Máa Ń Dárí Ji Ara Rẹ? July 24-30 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 21-23 Ẹni Tó Lẹ́tọ̀ọ́ Lábẹ́ Òfin Ni Ọba Tọ́ Sí MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Hùwà Tó Bójú Mu Lóde Ẹ̀rí July 31–August 6 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 24-27 Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Bí Ìlú Tírè Ṣe Máa Pa Run Mú Ká Fọkàn Tán Ọ̀rọ̀ Jèhófà