July 24-30
Ìsíkíẹ́lì 21-23
Orin 99 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ẹni Tó Lẹ́tọ̀ọ́ Lábẹ́ Òfin Ni Ọba Tọ́ Sí”: (10 min.)
Isk 21:25—Ọba Sedekáyà ni “ìjòyè burúkú ti Ísírẹ́lì” (w07 7/1 13 ¶11)
Isk 21:26—Ìṣàkóso àwọn ọba tó ń jẹ ní ìlà ìdílé Dáfídì ní Jerúsálẹ́mù máa dópin (w11 8/15 9 ¶6)
Isk 21:27—Jésù Kristi ni “ẹni tí ó ní ẹ̀tọ́ lọ́nà òfin” (w14 10/15 10 ¶14)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Isk 21:3—Kí ni “idà” tí Jèhófà mú jáde kúrò nínú àkọ̀ rẹ̀? (w07 7/1 14 ¶1)
Isk 23:49—Àṣìṣe wo ni orí ìkẹtàlélógún sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀, kí la sì rí kọ́? (w07 7/1 14 ¶6)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 21:1-13
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg—Sọ̀rọ̀ nípa fídíò náà Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? kí ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh—Sọ̀rọ̀ nípa fídíò náà Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? pẹ̀lú ẹnì kan tó o máa ń fún ní ìwé ìròyìn déédéé, kí ẹ sì jíròrò rẹ̀ (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó).
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 215 ¶3–216 ¶1
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Máa Hùwà Tó Bójú Mu Lóde Ẹ̀rí”: (15 min.) Ìjíròrò. Alábòójútó iṣẹ́ ìsìn ni kó bójú tó apá yìí. Jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ wo fídíò tó sọ̀rọ̀ nípa bá a ṣe lè máa hùwà tó bójú mu lóde ẹ̀rí.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 15 ¶18-28
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 29 àti Àdúrà