October 2-8
DÁNÍẸ́LÌ 7-9
Orin 116 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì Sọ Ìgbà Tí Mèsáyà Máa Dé”: (10 min.)
Da 9:24—Ikú ìrúbọ tí Mèsáyà kú ló mú kí Ọlọ́run lè máa dárí ẹ̀ṣẹ̀ jì wá (it-2 902 ¶2)
Da 9:25—Mèsáyà náà dé ní òpin ọ̀sẹ̀ mọ́kàndínláàádọ́rin [69] ti ọdún (it-2 900 ¶7)
Da 9:26, 27a—Wọ́n pa Mèsáyà náà ní àárín àádọ́rin ọ̀sẹ̀ [70] ti ọdún (it-2 901 ¶2, 5)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Da 9:24—Ìgbà wo ni a fòróró yan “Ibi Mímọ́ nínú Àwọn Ibi Mímọ́”? (w01 5/15 27)
Da 9:27—Májẹ̀mú wo ló ń ṣiṣẹ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ títí di òpin àádọ́rin ọ̀sẹ̀ ti ọdún, tàbí ọdún 36 Sànmánì Kristẹni? (w07 9/1 20 ¶4)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Da 7:1-10
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò tó dá lórí “Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò.” Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. Gba àwọn ará níyànjú kí wọ́n tètè pa dà lọ sọ́dọ̀ àwọn tó fìfẹ́ hàn.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Jinlẹ̀ Nínú Ìwé Mímọ́”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Àwọn Ohun Èlò Ìwádìí Tá A Fi Ń Wá Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 19 ¶1-7, àwọn àpótí “Ṣọ́ọ̀ṣì “New Light”” àti “Iṣẹ́ Kíkọ́ Ẹ̀ka Ọ́fíìsì —Àtúntò Látàrí Ìyípadà Tó Ń Wáyé”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 53 àti Àdúrà