October Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé October 2017 Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò October 2-8 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | DÁNÍẸ́LÌ 7-9 Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì Sọ Ìgbà Tí Mèsáyà Máa Dé MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Jinlẹ̀ Nínú Ìwé Mímọ́ October 9-15 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | DÁNÍẸ́LÌ 10-12 Jèhófà Mọ Ohun Tó Máa Ṣẹlẹ̀ sí Àwọn Ọba October 16-22 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | HÓSÉÀ 1-7 Ṣé Inú Rẹ Máa Ń Dùn sí Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Bíi Ti Jèhófà? October 23-29 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | HÓSÉÀ 8-14 Fún Jèhófà Ní Ohun Tó Dára Jù Lọ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Fi Ayé Rẹ Yin Jèhófà! October 30–November 5 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÓẸ́LÌ 1-3 ‘Àwọn Ọmọkùnrin Yín àti Àwọn Ọmọbìnrin Yín Yóò Máa Sọ Tẹ́lẹ̀’