October 23-29
HÓSÉÀ 8-14
Orin 153 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Fún Jèhófà Ní Ohun Tó Dára Jù Lọ”: (10 min.)
Ho 14:2—Jèhófà mọyì bá a ṣe ń fi ẹnu wa yìn ín (w07 4/1 20 ¶2)
Ho 14:4—Jèhófà máa ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ ji àwọn tó ń mú irú ẹbọ ìyìn bẹ́ẹ̀ wá, ó máa ń tẹ́wọ́ gbà wọ́n, ó sì máa ń bá wọn dọ́rẹ̀ẹ́ (w11 2/15 16 ¶15)
Ho 14:9—Àǹfààní wà nínú ká máa tẹ̀ lé àwọn ìlànà Jèhófà (jd 87 ¶11)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Ho 10:12—Kí la lè ṣe láti jọlá ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀? (w05 11/15 28 ¶7)
Ho 11:1—Báwo ni ọ̀rọ̀ yìí ṣe ṣẹ sí Jésù lára? (w11 8/15 10 ¶10)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ho 8:1-14
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-35
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) T-35—Nígbà tó o kọ́kọ́ wàásù fún ẹni náà, o ti fún un ní ìwé àṣàrò kúkúrú yìí. Máa bá ìjíròrò náà lọ, kí o sì ṣàlàyé kókó kan tí onílé sọ pé òun ò fara mọ́.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 152 ¶13-15—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Fi Ayé Rẹ Yin Jèhófà!”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Lo Ẹ̀bùn Ẹ Fún Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 20 ¶7-16, àpótí “Ìwé Kan Tó Wà Fáwọn Tó Ń Ṣe Iṣẹ́ Ìrànwọ́ Nígbà Àjálù”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 63 àti Àdúrà