ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | HÓSÉÀ 8-14
Fún Jèhófà Ní Ohun Tó Dára Jù Lọ
Inú Jèhófà máa dùn tó o bá fún un ní ohun tó dára jù lọ, ó sì máa ṣe ìwọ náà láǹfààní
ÀJỌṢE RẸ PẸ̀LÚ JÈHÓFÀ
O rú ẹbọ ìyìn sí Jèhófà
Jèhófà dárí jì ẹ́, ó tẹ́wọ́ gbà ẹ́, o sì di ọ̀rẹ́ rẹ̀
Wàá rí àǹfààní tó wà nínú kéèyàn máa ṣègbọràn sí àwọn àṣẹ Jèhófà, èyí á sì jẹ́ kó máa wù ẹ́ láti túbọ̀ máa yìn ín
Àwọn ọ̀nà wo ni mo lè gbà fún Jèhófà ní ohun tó dára jù?