October 16-22
HÓSÉÀ 1-7
Orin 18 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ṣé Inú Rẹ Máa Ń Dùn sí Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Bíi Ti Jèhófà?”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Hóséà.]
Ho 6:4, 5—Inú Jèhófà kò dùn sí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì torí pé wọn ò ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ (w10 8/15 25 ¶18)
Ho 6:6—Inú Jèhófà máa ń dùn sí wa tá a bá ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ (w07 9/15 16 ¶8; w07 6/15 27 ¶7)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Ho 1:7—Ìgbà wo ni Jèhófà fi àánú hàn sí ilé Júdà tó sì gbà wọ́n là? (w07 9/15 14 ¶7)
Ho 2:18—Báwo ni ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe ṣẹ nígbà àtijọ́, báwo ló sì ṣe máa ṣẹ lọ́jọ́ iwájú? (w05 11/15 20 ¶16; g05-E 9/8 12 ¶2)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ho 7:1-16
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Jo 5:3—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni—Pe ẹni náà wá sí àwọn ìpàdé wa.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Di 30:11-14; Ais 48:17, 18—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni—Sọ fún ẹni náà nípa ìkànnì jw.org. (Wo mwb16.08 8 ¶2.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 12-13 ¶16-18 —Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.) Alàgbà ni kó sọ àsọyé yìí. Mú ọ̀rọ̀ oníṣẹ̀ẹ́jú-márùn-ún tá a gbé ka Ìwé Mímọ́ tó o máa fi nasẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ jáde láti inú Ilé Ìṣọ́ November 15, 2015, ojú ìwé 14. Lẹ́yìn náà jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Bá A Ṣe Lè Fi Owó Ṣètìlẹ́yìn Látorí Íńtánẹ́ẹ̀tì. Tẹ́ ẹ bá ti wo fídíò náà tán, fi abala “Bó O Ṣe Lè Fi Ọrẹ Ti Iṣẹ́ Tá À Ń Ṣe Kárí Ayé Lẹ́yìn” han àwọn ará lórí ìkànnì jw.org/yo. Kí o sì ṣàlàyé oríṣiríṣi àbá tó wà níbẹ̀ nípa ọ̀nà tí èèyàn lè gbà ṣètìlẹ́yìn lórí ìkànnì lórílẹ̀-èdè yín.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 20 ¶1-6, àwọn àpótí “Ètò Ìrànwọ́ Àkọ́kọ́ Tó Kárí Ayé Lóde Òní,” “Bí A Ṣe Lè Múra Sílẹ̀ De Àjálù,” and “Nígbà Tí Àjálù Bá Ṣẹlẹ̀!”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 50 àti Àdúrà