October 9-15
DÁNÍẸ́LÌ 10-12
Orin 31 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jèhófà Mọ Ohun Tó Máa Ṣẹlẹ̀ sí Àwọn Ọba”: (10 min.)
Da 11:2—Àwọn ọba mẹ́rin díde ní Ilẹ̀ Ọba Páṣíà (dp 212-213 ¶5-6)
Da 11:4—Ìjọba Alẹkisáńdà pín sí apá mẹ́rin (dp 214 ¶11)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Da 12:3—Àwọn wo ni “àwọn tí ó ní ìjìnlẹ̀ òye,” ìgbà wo ni wọ́n sì “máa tàn bí ìtànyòò òfuurufú”? (w13 7/15 13 ¶16, àfikún àlàyé)
Da 12:13—Báwo ni Dáníẹ́lì ṣe máa “dìde”? (dp 315 ¶18)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Da 11:28-39
APPLY YOURSELF TO THE FIELD MINISTRY
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.5 —Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g17.5 —Nígbà tó o kọ́kọ́ wàásù fún ẹni náà, o ti fún un ní ìwé ìròyìn yìí. Máa bá ìjíròrò náà lọ kí o sì jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.
Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w16.11 5-6 ¶7-8—Àkòrí: Báwo La Ṣe Lè Máa Fúnni Níṣìírí Bíi Ti Jèhófà?
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì Ń Fúnni Lókun: (15 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà “Ọ̀rọ̀ Àsọtẹ́lẹ̀” Ń Fúnni Lokun.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 19 ¶8-18, àpótí tó wà fún àtúnyẹ̀wò “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 126 àti Àdúrà