ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 November ojú ìwé 2
  • November 6-12

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 6-12
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 November ojú ìwé 2

November 6-12

ÁMÓSÌ 1-9

  • Orin 144 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Wá Jèhófà, Kí O sì Máa Wà Láàyè Nìṣó”: (10 min.)

    • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ámósì.]

    • Amo 5:​4, 6​—A gbọ́dọ̀ mọ Jèhófà kí a sì máa ṣe ìfẹ́ rẹ̀ (w04 11/⁠15 24 ¶20)

    • Amo 5:​14, 15​—A gbọ́dọ̀ fara mọ́ àwọn ìlànà Jèhófà nípa ohun tó tọ́ àtohun tí kò tọ́, ká sì nífẹ̀ẹ́ àwọn ìlànà náà (jd 90-91 ¶16-17)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Amo 2:12​—Báwo ni a ṣe lè fi ẹ̀kọ́ tó wà nínú ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí sílò lónìí? (w07 10/⁠1 14 ¶8)

    • Amo 8:​1, 2​—Kí ni “apẹ̀rẹ̀ èso ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn kan” dúró fún? (w07 10/⁠1 14 ¶6)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Amo 4:​1-13

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò tó dá lórí “Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò.” Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 141

  • “Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I​—Máa Ṣe Ìpadàbẹ̀wò”: (15 min.) Ìjíròrò. Lẹ́yìn náà, jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò àwọn akéde méjì tó ń ṣe ìpadàbẹ̀wò, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr “Apá 7​—Àwọn Ìlérí Ìjọba Ọlọ́run—Ó Ń Sọ Ohun Gbogbo Di Ọ̀tun,” orí 21 ¶1-7

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 128 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́