November 13-19
ỌBADÁYÀ 1–JÓNÀ 4
Orin 42 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Àwọn Àṣìṣe Rẹ”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ọbadáyà.]
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jónà.]
Jon 3:1-3—Jónà kẹ́kọ̀ọ́ nínú àwọn àṣìṣe rẹ̀ (ia 114 ¶22-23)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Ọbd 10—Báwo la ṣe “ké [Édómù] kúrò fún àkókò tí ó lọ kánrin”? (w07 11/1 13 ¶5)
Ọbd 12—Kí la rí kọ́ nínú bí Ọlọ́run ṣe kéde ìdájọ́ sórí Édómù? (jd 112 ¶4-5)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jon 3:1-10
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn wp17.6—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) wp17.6—Nígbà tó o kọ́kọ́ wàásù fún ẹni náà, o ti fún un ní ìwé ìròyìn yìí. Ṣe ìpadàbẹ̀wò, kó o sì fi ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tá a fi ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì hàn án.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) ld 12-13—Yan àwòrán tẹ́ ẹ máa jíròrò.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ẹ̀kọ́ Tó Wà Nínú Ìwé Jónà”: (15 min.) Ẹ jíròrò àpilẹ̀kọ yìí lẹ́yìn tí ẹ bá ti wo fídíò Ìjọsìn Ìdílé: Jónà—Kọ́ Bí O Ṣe Lè Jẹ́ Aláànú Bíi Ti Jèhófà.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 21 ¶8-14
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 133 àti Àdúrà