ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 February ojú ìwé 2
  • February 5-11

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • February 5-11
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 February ojú ìwé 2

February 5-11

MÁTÍÙ 12-13

  • Orin 27 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Àkàwé Àlìkámà àti Èpò”: (10 min.)

    • Mt 13:​24-26​—Ọkùnrin kan fún irúgbìn àtàtà sínú pápá rẹ̀, ọ̀tá rẹ̀ wá, ó sì fún àwọn èpò sí àárín pápá náà (w13 7/15 9-10 ¶2-3)

    • Mt 13:​27-29​—Àlìkámà àti èpò dàgbà pa pọ̀ títí di ìgbà ìkórè (w13 7/15 10 ¶4)

    • Mt 13:30​—Nígbà ìkórè, àwọn olùkórè kọ́kọ́ kó èpò, wọ́n sì gbá àlìkámà jọ (w13 7/15 12 ¶10-12)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Mt 12:20​—Báwo la ṣe lè máa fi àánú hàn bíi ti Jésù? (“Òwú àtùpà” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 12:20, nwtsty)

    • Mt 13:25​—Ṣé òótọ́ ni pé láyé àtijọ́, ó ṣeé ṣe kí ẹnì kan fún èpò sínú pápá ẹlòmíì? (w16.10 32)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mt 12:1-21

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́​—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìpadàbẹ̀wò àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 21-23 ¶10-12

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 68

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)

  • “Àǹfààní Tá A Lè Rí Nínú Ìtumọ̀ Àwọn Àpèjúwe Ìjọba Ọlọ́run”: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ jíròrò bí àwọn àpèjúwe yìí ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv àfikún Ọwọ́ Tó Yẹ Ká Fi Mú Ẹni Tí Wọ́n Bá Yọ Lẹ́gbẹ́

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 10 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́