February Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé February 2018 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ February 5-11 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 12-13 Àkàwé Àlìkámà àti Èpò MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àǹfààní Tá A Lè Rí Nínú Ìtumọ̀ Àwọn Àpèjúwe Ìjọba Ọlọ́run February 12-18 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 14-15 Jésù Ń Tipasẹ̀ Àwọn Èèyàn Kéréje Bọ́ Ọ̀pọ̀ Èèyàn MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI “Bọlá fún Baba Rẹ àti Ìyá Rẹ” February 19-25 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 16-17 Èrò Ta Ni Ò Ń Rò? MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Lo Ìbéèrè Lọ́nà Tó Gbéṣẹ́ February 26–March 4 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 18-19 Yẹra Pátápátá fún Ohun Tó Lè Mú Ìwọ Àtàwọn Mí ì Kọsẹ̀