ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 March ojú ìwé 2
  • March 5-11

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 5-11
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 March ojú ìwé 2

March 5-11

MÁTÍÙ 20-21

  • Orin 76 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ẹnì Yòówù Tí Ó Bá Fẹ́ Di Ẹni Ńlá Láàárín Yín Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Òjíṣẹ́ Yín”: (10 min.)

    • Mt 20:3​—Àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn Farisí onígbèéraga fẹ́ràn káwọn èèyàn máa kí wọn “ní ibi ọjà” (“Ibi Ọjà” àwòrán àti fídíò lórí Mt 20:3, nwtsty)

    • Mt 20:​20, 21​—Àwọn àpọ́sítélì méjì béèrè fún ipò ọlá àti ipò àṣẹ (“ìyá àwọn ọmọkùnrin Sébédè,” “ọ̀kan ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ àti ọ̀kan ní òsì rẹ” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 20:20, 21, nwtsty)

    • Mt 20:​25-28​—Jésù sọ pé ó yẹ kí àwọn ọmọ ẹ̀yìn òun jẹ́ òjíṣẹ́ tó nírẹ̀lẹ̀ (“òjíṣẹ́,” “kì í ṣe kí a lè ṣe ìránṣẹ́ fún un, bí kò ṣe kí ó lè ṣe ìránṣẹ́” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 20:26, 28, nwtsty)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Mt 21:9​—Nígbà táwọn èrò kígbe pé: “Gba Ọmọkùnrin Dáfídì là, ni àwa bẹ̀bẹ̀!” kí ni wọ́n ní lọ́kàn? (“Gbà là, ni àwa bẹ̀bẹ̀,” “Ọmọkùnrin Dáfídì” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 21:9, nwtsty)

    • Mt 21:​18, 19​—Kí nìdí tí Jésù fi sọ fún igi ọ̀pọ̀tọ́ náà pé kó rọ? (jy 244 ¶4-6)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mt 20:​1-19

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́​—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Wo Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 36-37 ¶3-4

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 99

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)

  • Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù March.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv àfikún àlàyé Ìgbà Wo Ló Yẹ Kí Obìnrin Máa Borí, Kí sì Nìdí?

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 53 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́