March Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, March 2018 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ March 5-11 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 20-21 “Ẹnì Yòówù Tí Ó Bá Fẹ́ Di Ẹni Ńlá Láàárín Yín Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Òjíṣẹ́ Yín” March 12-18 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 22-23 Máa Tẹ̀ Lé Àwọn Àṣẹ Méjì Tó Tóbi Jù Lọ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Bí A Ṣe Lè Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run Àtàwọn Aládùúgbò Wa March 19-25 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 24 Máa Wà Lójúfò Nípa Tẹ̀mí ní Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn Yìí MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Òpin Ètò Àwọn Nǹkan Yìí Ti Sún Mọ́ Gan-an March 26–April 1 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 25 “Ẹ Máa Bá A Nìṣó ní Ṣíṣọ́nà” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Kọ́ Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Rẹ Bí Wọ́n Á Ṣe Máa Múra Ìkẹ́kọ̀ọ́ Sílẹ̀