ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 March ojú ìwé 5
  • Òpin Ètò Àwọn Nǹkan Yìí Ti Sún Mọ́ Gan-an

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Òpin Ètò Àwọn Nǹkan Yìí Ti Sún Mọ́ Gan-an
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1997
  • Àkókò Láti Wà Lójúfò
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1995
  • Wíwàníhìn-ín Kristi—Báwo Ló Ṣe Yé ọ sí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
  • A Gbà Wọ́n Là Láti Inú “Ìran Burúkú”
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1995
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 March ojú ìwé 5
Jésù ń bá Pétérù, Áńdérù, Jákọ́bù àti Jòhánù sọ̀rọ̀

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Òpin Ètò Àwọn Nǹkan Yìí Ti Sún Mọ́ Gan-an

Wo fídíò náà Òpin Ètò Àwọn Nǹkan Yìí Ti Sún Mọ́ Gan-an, kó o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tó wà nísàlẹ̀ yìí tó dá lórí Mátíù 24:34.

Àtẹ àwọn ọjọ́ ìṣẹ̀lẹ̀ nípa “ìran yìí”
  • Kí ni “gbogbo nǹkan wọ̀nyí”?

  • Báwo ni Ẹ́kísódù 1:6 ṣe ràn wá lọ́wọ́ láti mọ ìtumọ́ ọ̀rọ̀ náà “ìran”?

  • Ìran wo ní pàtàkì ni Jésù ń tọ́ka sí?

  • Àwùjọ méjì wo ló para pọ̀ di “ìran yìí”?

  • Báwo ni ọ̀rọ̀ Jésù ṣe fi hàn pé òpin ètò àwọn nǹkan yìí ti sún mọ́ gan-an?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́