ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 March ojú ìwé 6
  • March 26–April 1

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 26–April 1
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 March ojú ìwé 6

March 26–April 1

MÁTÍÙ 25

  • Orin 143 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ẹ Máa Bá A Nìṣó ní Ṣíṣọ́nà”: (10 min.)

    • Mt 25:​1-6​—Àwọn wúńdíá olóye márùn-ún àtàwọn wúńdíá òmùgọ̀ márùn-ún jáde lọ pàdé ọkọ ìyàwó

    • Mt 25:​7-10​—Àwọn wúńdíá òmùgọ̀ náà kò sí níbẹ̀ nígbà tí ọkọ ìyàwó dé

    • Mt 25:​11, 12​—Àwọn wúńdíá olóye nìkan ló wọlé síbi àsè ìgbéyàwó náà

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Mt 25:​31-33​—Ṣàlàyé àpèjúwe àwọn àgùntàn àtàwọn ewúrẹ́. (w15 3/15 27 ¶7)

    • Mt 25:40​—Ọ̀nà wo la lè gbà fi hàn pé a jẹ́ ọ̀rẹ́ àwọn arákùnrin Kristi? (w09 10/15 16 ¶16-18)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mt 25:​1-23

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Pe ẹni náà wá sí Ìrántí Ikú Kristi.

  • Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwọ ni kó o yan ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tó o máa lò, fi ọ̀kan nínú àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ lọ̀ ọ́.

  • Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w15 3/15 27 ¶7-10​—Àkòrí: Báwo Ni Àpèjúwe Àwọn Àgùntàn Àtàwọn Ewúrẹ́ Ṣe Fi Hàn Pé Iṣẹ́ Ìwàásù Ṣe Pàtàkì?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 85

  • “Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I​—Kọ́ Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Rẹ Bí Wọ́n Á Ṣe Máa Múra Ìkẹ́kọ̀ọ́ Sílẹ̀”: (10 min.) Ìjíròrò. Lẹ́yìn náà, jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò bí akéde kan ṣe ń kọ́ akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì rẹ̀ bó ṣe máa múra ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ sílẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. Ní káwọn ará sọ àwọn ọ̀nà míì tó gbéṣẹ́ tí wọ́n ń gbà kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì wọn láti máa múra ìkẹ́kọ̀ọ́ wọn sílẹ̀.

  • Ẹ Kí Àwọn Tá A Pè Káàbọ̀: (5 min.) Àsọyé tó dá lórí àpilẹ̀kọ tó wà nínú Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ti March 2016. Sọ àwọn ìrírí tó gbádùn mọ́ni tẹ́ ẹ ní nígbà Ìrántí Ikú Kristi ti ọdún 2017. Rán àwọn ará létí àwọn ohun pàtàkì nípa Ìrántí Ikú Kristi tó ń bọ̀ ní March 31, bí àpẹẹrẹ, ibi ìgbọ́kọ̀sí, bí wọ́n ṣe máa wọlé àti bí wọ́n á ṣe jáde àtàwọn nǹkan míì tó pọn dandan.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 5 ¶16-23

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 79 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́