ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 March ojú ìwé 3
  • March 12-18

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 12-18
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 March ojú ìwé 3

March 12-18

MÁTÍÙ 22-23

  • Orin 30 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Máa Tẹ̀ Lé Àwọn Àṣẹ Méjì Tó Tóbi Jù Lọ”: (10 min.)

    • Mt 22:​36-38​—Báwo ni àwọn ẹsẹ yìí ṣe ṣàlàyé ohun tó ní nínú láti tẹ̀ lé àṣẹ títóbi jù lọ àti èkíní nínú Òfin? (“ọkàn-àyà,” “ọkàn,” “èrò inú” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 22:37, nwtsty)

    • Mt 22:39​—Kí ni àṣẹ títóbi jù lọ kejì nínú Òfin? (“Èkejì,” “aládùúgbò” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 22:39, nwtsty)

    • Mt 22:40​—Orí ìfẹ́ ni gbogbo Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù dá lé (“Òfin . . . àwọn Wòlíì,” “so kọ́” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 22:40, nwtsty)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Mt 22:21​—Kí ni “àwọn ohun ti Késárì,” kí sì ni “àwọn ohun ti Ọlọ́run”? (“àwọn ohun ti Késárì padà fún Késárì,” “àwọn ohun ti Ọlọ́run fún Ọlọ́run” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 22:21, nwtsty)

    • Mt 23:24​—Kí ni ọ̀rọ̀ Jésù yìí túmọ̀ sí? (“tí ń sẹ́ kòkòrò kantíkantí ṣùgbọ́n tí ń gbé ràkúnmí mì káló” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 23:24, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mt 22:​1-22

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Wo Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ.

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́​—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 186-187 ¶7-8​—Kí olùkọ́ gba akẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ níyànjú pé kó pe àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ wá sí Ìrántí Ikú Kristi.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 96

  • “Bí A Ṣe Lè Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run Àtàwọn Aládùúgbò Wa”: (15 min.) Ìjíròrò. Ká lè rí àǹfààní tó wà nínú kéèyàn máa fọkàn yàwòrán àwọn ìtàn inú Bíbélì, jẹ́ kí àwọn ará gbọ́ díẹ̀ nínú Bíbélì kíkà bí ẹni ṣe eré ìtàn tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Jèhófà Nìkan Ṣoṣo Ni Ọlọ́run Tòótọ́, kí wọ́n máa fojú bá ìtàn tó wà ní 1 Àwọn Ọba 18:​17-46 lọ nínú Bíbélì wọn.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 5 ¶1-6 àti àpótí ojú ìwé 52 àti 55

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 52 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́