ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 March ojú ìwé 4
  • March 19-25

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 19-25
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 March ojú ìwé 4

March 19-25

MÁTÍÙ 24

  • Orin 126 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Máa Wà Lójúfò Nípa Tẹ̀mí ní Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn Yìí”: (10 min.)

    • Mt 24:12​—Ìwà àìlófin tó ń pọ̀ sí i máa jẹ́ kí ìfẹ́ àwọn èèyàn di tútù (it-2 279 ¶6)

    • Mt 24:39​—Bí àwọn kan ṣe máa gbé ìgbé ayé ìdẹ̀rùn ló máa gbà wọ́n lọ́kàn, tí wọn ò sì ní lè wà lójúfò (w99 11/15 19 ¶5)

    • Mt 24:44​—Ọ̀gá náà máa dé nígbà tí a kò rò tẹ́lẹ̀ (jy 259 ¶5)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Mt 24:8​—Kí ló ṣeé ṣe kí ọ̀rọ̀ Jésù yìí tọ́ka sí? (“ìroragógó wàhálà” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 24:8, nwtsty)

    • Mt 24:20​—Kí nìdí tí Jésù fi sọ ọ̀rọ̀ yìí? (“ní ìgbà òtútù,” “ní ọjọ́ sábáàtì” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 24:20, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mt 24:​1-22

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Dáhùn ìbéèrè kan táwọn èèyàn sábà máa ń béèrè tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù ní ìpínlẹ̀ yín.

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Ẹni tó o kọ́kọ́ wàásù fún kò sí nílé, àmọ́ mọ̀lẹ́bí rẹ̀ kan lo bá.

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì​—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 57

  • “Òpin Ètò Àwọn Nǹkan Yìí Ti Sún Mọ́ Gan-an”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 5 ¶7-15

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 97 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́