ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 April ojú ìwé 2
  • April 2-8

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • April 2-8
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 April ojú ìwé 2

April 2-8

MÁTÍÙ 26

  • Orin 19 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ìyàtọ̀ àti Ìjọra Tó Wà Láàárín Ìrékọjá àti Ìrántí Ikú Kristi”: (10 min.)

    • Mt 26:​17-20​—Jésù jẹ Ìrékọjá tó kẹ́yìn pẹ̀lú àwọn àpọ́sítélì rẹ̀ (“Oúnjẹ Ìrékọjá” àwòrán àti fídíò lórí Mt 26:18, nwtsty)

    • Mt 26:26​—Búrẹ́dì tá a máa ń lò nígbà Ìrántí Ikú Kristi ṣàpẹẹrẹ ara Jésù (“túmọ̀ sí” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 26:26, nwtsty)

    • Mt 26:​27, 28​—Wáìnì tá a máa ń lò nígbà Ìrántí Ikú Kristi ṣàpẹẹrẹ “ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú” Jésù (“ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 26:28, nwtsty)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Mt 26:17​—Kí nìdí tí wọ́n fi pe Nísàn 13 ní “ọjọ́ kìíní àkàrà aláìwú”? (“Ní ọjọ́ kìíní àkàrà aláìwú” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 26:17, nwtsty)

    • Mt 26:39​—Kí ló ṣeé ṣe kó mú kí Jésù gbàdúrà pé: “Jẹ́ kí ife yìí ré mi kọjá”? (“jẹ́ kí ife yìí ré mi kọjá” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 26:39, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mt 26:​1-19

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́​—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 55 ¶21-22

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 20

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (8 min.)

  • Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Ìràpadà: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, pe àwọn ọmọdé bíi mélòó kan wá sórí pèpéle, kó o sì bi wọ́n pé: Kí nìdí tàwọn èèyàn fi ń ṣàìsàn, tí wọ́n ń darúgbó, tí wọ́n sì ń kú? Ìlérí wo ni Jèhófà ṣe? Ta lo máa fẹ́ rí nínú Párádísè?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv àfikún “Kíkí Àsíá, Dídìbò àti Sísin Ìlú Ẹni”

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 74 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́