ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 April ojú ìwé 3
  • April 9-15

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • April 9-15
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 April ojú ìwé 3

April 9-15

MÁTÍÙ 27-28

  • Orin 69 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ẹ Lọ Sọ Àwọn Ènìyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn​—Kí Nìdí, Níbo àti Báwo?”: (10 min.)

    • Mt 28:18​—Ọlá àṣẹ Jésù gbòòrò gan-an (w04 7/1 8 ¶4)

    • Mt 28:19​—Jésù pàṣẹ pé ká máa wàásù kárí ayé, ká sì máa kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ (“sọ àwọn ènìyàn . . . di ọmọ ẹ̀yìn,” “àwọn ènìyàn gbogbo orílẹ̀-èdè” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 28:19, nwtsty)

    • Mt 28:20​—A gbọ́dọ̀ ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ kí wọ́n lè mọ àwọn ẹ̀kọ́ Jésù, kí wọ́n sì máa fi sílò (“ẹ máa kọ́ wọn” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 28:20, nwtsty)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Mt 27:51​—Kí ni aṣọ ìkélé tó ya sí méjì dúró fún? (“ìkélé,” “ibùjọsìn” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 27:51, nwtsty)

    • Mt 28:7​—Báwo ni ańgẹ́lì Jèhófà ṣe buyì kún àwọn obìnrin tó wá síbi ibojì Jésù? (“sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ pé a ti gbé e dìde” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 28:7, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mt 27:​38-54

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ.

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́​—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) g17.2 14​—Àkòrí: Ṣé Orí Àgbélébùú Ni Jésù Kú Sí?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 70

  • “Iṣẹ́ Ìwàásù àti Kíkọ́ni Ṣe Pàtàkì Láti Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn”: (15 min.) Ìjíròrò. Tẹ́ ẹ bá ń jíròrò kókó yìí, jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Máa Wàásù Nìṣó “Láìdábọ̀”​—Lọ́nà Àìjẹ́-Bí-Àṣà àti Láti Ilé-Dé-Ilé àti Máa Wàásù Nìṣó “Láìdábọ̀”​—Níbi Térò Pọ̀ Sí àti Máa Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 6 ¶1-9

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 73 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́