June 4-10
MÁÀKÙ 15-16
Orin 95 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Àsọtẹ́lẹ̀ Ṣẹ sí Jésù Lára”: (10 min.)
Mk 15:3-5—Ó dákẹ́ nígbà tí wọ́n fi ẹ̀sùn kàn án
Mk 15:24, 29, 30—Wọ́n ṣẹ́ kèké lórí aṣọ rẹ̀, wọ́n sì fi í ṣe yẹ̀yẹ́ (“pín ẹ̀wù àwọ̀lékè rẹ̀”, àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mk 15:24 nwtsty, “wọ́n á mi orí wọn síwá sẹ́yìn” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mk 15:29, nwtsty)
Mk 15:43, 46—Wọ́n sin òkú rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọlọ́rọ̀ (“Jósẹ́fù” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mk 15:43 nwtsty)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Mk 15:25—Kí ló ṣeé ṣe kó jẹ́ ìdí tí ìyàtọ̀ fi wà nínú ìgbà tí wọ́n kan Jésù mọ́gi? (“wákàtí kẹta”, àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mk 15:25, nwtsty)
Mk 16:8—Kí nìdí tí Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun lédè Gẹ̀ẹ́sì, tá a tún ṣe lọ́dún 2013 kò fi ní ìparí gígùn tàbí ìparí kúkúrú nínú ìwé Ìhìn Rere Máàkù? (“nítorí wọ́n ń bẹ̀rù” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mk 6:8, nwtsty)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mk 15:1-15
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jl ẹ̀kọ́ 2
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Máa Tẹ̀ Lé Ìṣísẹ̀ Kristi Pẹ́kípẹ́kí”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Orúkọ Jèhófà Ló Ṣe Pàtàkì Jù.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 8 ¶11-18
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 140 àti Àdúrà