June Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, June 2018 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ June 4-10 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁÀKÙ 15-16 Àsọtẹ́lẹ̀ Ṣẹ sí Jésù Lára MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Tẹ̀ Lé Ìṣísẹ̀ Kristi Pẹ́kípẹ́kí June 11-17 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÚÙKÙ 1 Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀ Màríà June 18-24 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÚÙKÙ 2-3 Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ṣé Àjọṣe Yín Pẹ̀lú Jèhófà Túbọ̀ Ń Lágbára Sí I? MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Ran Àwọn Ọmọ Yín Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣàṣeyọrí June 25–July 1 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÚÙKÙ 4-5 Kọ Ìdẹwò Bí I Ti Jésù MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ṣọ́ra fún Àwọn Ewu Tó Wà Nínú Ìkànnì Àjọlò