ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 June ojú ìwé 5
  • June 18-24

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • June 18-24
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 June ojú ìwé 5

June 18-24

Lúùkù 2-3

  • Orin 133 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ṣé Àjọṣe Yín Pẹ̀lú Jèhófà Túbọ̀ Ń Lágbára Sí I?”: (10 min.)

    • Lk 2:41, 42​—Jésù àti àwọn òbí rẹ̀ jọ máa ń lọ sí àjọyọ̀ Ìrékọjá ọdọọdún (“ó jẹ́ àṣà àwọn òbí rẹ̀” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 2:41, 42, nwtsty)

    • Lk 2:46, 47​—Jésù tẹ́tí sí àwọn aṣáájú ẹ̀sìn, ó sì bi wọ́n ní ìbéèrè (“ó sì ń bi wọ́n ní ìbéèrè,” “wọ́n ń ṣe kàyéfì léraléra” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 2:46, 47, nwtsty)

    • Lk 2:51, 52​—Jésù “ń bá a lọ ní fífi ara rẹ̀ sábẹ́” àwọn òbí rẹ̀, ó sì rí ojú rere Ọlọ́run àti èèyàn (“bá a lọ ní fífi ara rẹ̀ sábẹ́ wọn” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 2:51, 52, nwtsty)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Lk 2:14​—Kí ni ìtumọ̀ Lúùkù 2:14? (“àti lórí ilẹ̀ ayé àlàáfíà láàárín àwọn ẹni ìtẹ́wọ́gbà,” “àwọn ẹni ìtẹ́wọ́gbà” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 2:14, nwtsty)

    • Lk 3:23​—Ta ni bàbá Jósẹ́fù? (wp16.3 9 ¶1-3)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lk 2:1-20

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, dáhùn ìbéèrè kan táwọn èèyàn sábà máa ń béèrè ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù.

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì​—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w14 2/15 26-27​—Àkòrí: Kí Ló Mú Kí Àwọn Júù Ọ̀rúndún Kìíní Máa “Fojú Sọ́nà” fún Mèsáyà?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 134

  • “Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Ran Àwọn Ọmọ Yín Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣàṣeyọrí”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Wọ́n Gbá Àǹfààní Tó Ṣí Sílẹ̀ Mú.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 9 ¶1-12 àti Ohun Tó Ràn Mí Lọ́wọ́ Láti Jáwọ́ Nínú Ìṣekúṣe [Kò pọn dandan kẹ́ ẹ ka àpótí tàbí àfikún àlàyé]

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 17 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́