June 11-17
LÚÙKÙ 1
Orin 137 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀ Màríà”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Lúùkù.]
Lk 1:38—Ó fi ìrẹ̀lẹ̀ tẹ́wọ́ gba iṣẹ́ tí Ọlọ́run fún un (ia 149 ¶12)
Lk 1:46-55—Ó yin Jèhófà bó ṣe ń tọ́ka sí Ọ̀rọ̀ rẹ̀ (ia 150-151 ¶15-16)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Lk 1:69—Kí ni ìtúmọ̀ ọ̀rọ̀ náà “ìwo ìgbàlà kan”? (“ìwo ìgbàlà kan” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 1:69, nwtsty)
Lk 1:76—Ọ̀nà wo ni Jòhánù Oníbatisí gbà “lọ ṣáájú níwájú Jèhófà”? (“ìwọ yóò lọ ṣáájú níwájú Jèhófà” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 1:76, nwtsty)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lk 1:46-66
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ.
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (8 min.) Tàbí kẹ́ ẹ jíròrò àlàyé tó dá lórí ẹsẹ Ìwé Mímọ́ ọdún 2018. (w18.01 8-9 ¶4-7)
Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù June.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 8 ¶19-26 àti àpótí ojú ìwé Ṣé Mò Ń Sapá Gidigidi Láti Ṣe Ohun Tọ́ Tọ́? àti “Lọ́dọ̀ Ọlọ́run Ohun Gbogbo Ṣeé Ṣe”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 58 àti Àdúrà